Orüko Âmutorunwa – Basic 5 Yoruba Lesson Note (First Term)
Download this term · ₦1,000Lesson note at a glance
- Subject
- Yoruba
- Class
- Basic 5
- Term
- First Term
- Topic
- Orüko Âmutorunwa
- Order
- Topic 25 of 26 this term
- Reading time
- 1 min
Àfojúsùn ẹkọ́
Ní òpin ìdánilẹ́kọ̀ọ́, àwọn akẹ́kọ̀ọ́ yóò lè:
- Sọ ìtumọ̀ orúkọ àmútọ̀runwá
- Dárúkọ orúkọ àmútọ̀runwá ní ilẹ̀ Yorùbá
- Ṣàlàyé ìtumọ̀ tí ó rí mọ́ orúkọ àmútọ̀runwá
- Dahùn ìbéèrè lórí ẹ̀kọ́
Ìtumọ̀ orúkọ àmútọ̀runwá
Orúkọ àmútọ̀runwá ni àwọn orúkọ tí àwọn òbí máa ń sọ fún àwọn ọmọ wọn tí ó da lórí ìṣẹ̀lẹ̀ ìbí ọmọ.
Àwọn àpẹẹrẹ
- Ìgá – Ọmọ tí a bí sí ojú ọ̀nà
- Àìná – Ọmọ tí a bí pẹ̀lú okùn ọrùn yí sí ọrùn
- Ọjọ́ – Ọmọ ọkùnrin tí a bí ní ọjọ́ àìsàn
- Táíwò – Ọmọ àkọ́kọ́ nínú ìbejì
- Ìdówú – Ọmọ tí a bí lẹ́yìn ìbejì
- Ìdògbò – Ọmọ kẹta lẹ́yìn ìbejì
- Ìdòhẹ̀ – Ọmọ kẹrin lẹ́yìn ìbejì
- Àlàbá – Ọmọ karùn-ún lẹ́yìn ìbejì
Ìbéèrè
- Kí ni ìtumọ̀ orúkọ àmútọ̀runwá?
- Dárúkọ orúkọ mẹ́ta tí ó jẹ́ orúkọ àmútọ̀runwá
- Kí ni ìtumọ̀ Táíwò?
- Kí ni orúkọ ọmọ kẹta lẹ́yìn ìbejì?
Iṣẹ́ ilé
Kọ ìtumọ̀ orúkọ àmútọ̀runwá márùn-ún sínú ìwé yín.
This term's Yoruba topics
Basic 5 First Term · 26 topics
- Äröko Letå Kiko Orisisi Létå to Wa
- Eka Yoruba Ati Itankåle Won
- Éyå Ara Ifo
- Oge Sise Ni Ile Yoruba
- Orin Ayęyę Yoruba Bii Orin Iyawo, Orin Etiyęri
- Ônâ Ibănisęro Ni Ôde Oni
- Oruko Jiję Nile Yorubă
- Kikà Ewì Apilëko Àti Igbedegbe Ken Àti Yiyo Komookun, Ogbon Inu Ewi Naa
- Âròko Asàpejuwe
- Orüko Âmutorunwa
- Orin İremolekun
Get Yoruba as PDF and Word
Every week of Basic 5 Yoruba, First Term, formatted and ready to print. Ad-free, and the copy lock comes off.
Get this term Card, bank transfer, USSD or OPay

