Ede: Silebu Olorì Meta Ati Merin – Basic 2 Yoruba Lesson Note (Third Term)
Download Lesson NoteLesson note at a glance
- Subject
- Yoruba
- Class
- Basic 2
- Term
- Third Term
- Topic
- Ede: Silebu Olorì Meta Ati Merin
- Order
- Topic 25 of 27 this term
- Reading time
- 1 min
EDE – Silebu Olorì Meta ati Merin
Afojusun Ẹko:
- Pe orọ onisilebu meta
- Pe oro onisilebu merin daradara
- Dahun ibeere abe eko naa
Silebu Olorì Meta:
- a-ga-da
- i-ya-wo
- e-le-yi
- o-mo-ge
- a-la-ba
Silebu Olorì Merin:
- a-ka-ra-bá
- o-ni-ka-luku
- a-ba-ni-dagba
- o-lo-du-mare
Iṣẹ: Pin awọn oro wonyi si silebu: aburo, alakara, agbalagba, omidun
This term's Yoruba topics
Basic 2 Third Term · 27 topics
- Asa: Awọn Eṣo (2)
- Litereso: Alọ Onitan
- Ede: Awọn Ami Ohun
- Asa: Aṣo Wiwọ
- Litereso: Ere Onise: “Ere Dara Pupọ”
- Ede: Onka Ni Ede Yoruba (81-100)
- Asa: Awọn Awọ (3) – Onipele Keta
- Litereso: Orin Omode: “Wẹ Ki Ọmọ”
- Ede: Silebu Olorì Meta Ati Merin
- Asa: Ounje Ile Yoruba: Amala, Eba, Eko, Iyan
- Agbeyewo Isẹ Saa Kini Lori Ede, Asa Ati Litereso


