Skip to content

Agbeyewo Isẹ Saa Kini Lori Ede, Asa Ati Litereso – Basic 2 Yoruba Lesson Note (Third Term)

Download Lesson Note

Lesson note at a glance

Subject
Yoruba
Class
Basic 2
Term
Third Term
Topic
Agbeyewo Isẹ Saa Kini Lori Ede, Asa Ati Litereso
Order
Topic 27 of 27 this term
Reading time
1 min

Afojusun Agbeyewo: Dahun ibeere abe eko lori Ede, Asa ati Literaso

Awọn Koko-ọrọ Fun Agbeyewo:

EDE:

Advertisement
  • Silebu oro (meji, meta, merin)
  • Onka Yoruba (71-100)
  • Faweli ede Yoruba
  • Ami ohun

ASA:

  • Ounje ile Yoruba
  • Awọn awọ (onipele keji ati keta)
  • Awọn eṣo
  • Aṣọ wiwọ

LITERESO:

  • Alọ onitan
  • Itan aroṣo
  • Orin ọmọde
  • Ere onise

Iriri Agbeyewo: Awọn akẹkọọ yoo dahun awọn ibeere lori gbogbo koko-ọrọ ti a ti kọ lati ọsẹ marun-un de ọsẹ mokànlá.

This term's Yoruba topics

Basic 2 Third Term · 27 topics

  1. Asa: Awọn Eṣo (2)
  2. Litereso: Alọ Onitan
  3. Ede: Awọn Ami Ohun
  4. Asa: Aṣo Wiwọ
  5. Litereso: Ere Onise: “Ere Dara Pupọ”
  6. Ede: Onka Ni Ede Yoruba (81-100)
  7. Asa: Awọn Awọ (3) – Onipele Keta
  8. Litereso: Orin Omode: “Wẹ Ki Ọmọ”
  9. Ede: Silebu Olorì Meta Ati Merin
  10. Asa: Ounje Ile Yoruba: Amala, Eba, Eko, Iyan
  11. Agbeyewo Isẹ Saa Kini Lori Ede, Asa Ati Litereso
See all 27 Basic 2 Third Term Yoruba topics →
Advertisement

Lesson Notes for Other Classes