Lesson Notes
Topic: Aroko Asånyanjiyån
Àkóónú:
- Orí-ọ̀rọ̀: “Ilé-ìwé ìjọba dára jù ilé-ìwé àládàní lọ”
- Ìlànà: Ìfàárà, Àròyé, Ìparí
Àpẹẹrẹ: Ilé-ìwé ìjọba nílè káàbọ̀, ìkọ́ni dára, àwọn olùkọ́ tó pẹ. Ṣùgbọ́n ilé-ìwé àládàní ní ètò tó tayọ.