Skip to content

Ede (Language): Itesiwaju Ninu Kiki Alifaabeti Yoruba – Basic 2 Yoruba Lesson Note (First Term)

Download this term · ₦1,000

Lesson note at a glance

Subject
Yoruba
Class
Basic 2
Term
First Term
Topic
Ede (Language): Itesiwaju Ninu Kiki Alifaabeti Yoruba
Order
Topic 20 of 24 this term
Reading time
1 min

AFOJUSUN EKO (Learning Objectives):

Ni opin idanileko akeko yoo le: i. Ka leta alifaabeti ede Yoruba ii. Pe letter alifabeeti pẹlu awọn oro oro aseeda iii. Dahun ibeere abe eko naa

ALAYE (Explanation):

Alifabeeti ede Yoruba ni ipilẹ gbogbo kika ati kikọ. A gbọdọ mọ gbogbo leta ati bi a se nlo wọn.

Atunwo alifabeeti Yoruba:

A, B, D, E, Ẹ, F, G, Gb, H, I, J, K, L, M, N, O, Ọ, P, R, S, Ṣ, T, U, W, Y

Ọrọ aseeda fun letra kọọkan:

  • A = Aso, Ati, Agbon
  • B = Bata, Bi, Baba
  • D = Dada, Di, Odo
  • E = Eja, Ewu, Ẹnu
  • Ẹ = Ẹja, Ẹhin, Ẹkọ
  • F = Fofo, Fi, Funfun
  • G = Gangan, Gi, Goro

Iṣẹ akekọ:

  1. Ka alifabeeti ni pẹpẹ
  2. Wa oro ti o bẹrẹ pẹlu leta kọọkan
  3. Kọ wọn si iwe ẹkọ

 

This term's Yoruba topics

Basic 2 First Term · 24 topics

  1. Ede (Language): Itesiwaju Ninu Atakuroso
  2. Asa (Culture): Ikinni Asiko
  3. Lit (Literature): Kiko Awọn Orin Kee Kee Kee Lagbe Igi Orongbo
  4. Ede (Language): Onka Ni Ede Yoruba 31-50
  5. Asa (Culture): Imototo Ara Eni
  6. Lit (Literature): Itan Aroso Olorò Geere Ayoka Ati Igi Iroko
  7. Ede (Language): Itesiwaju Ninu Kiki Alifaabeti Yoruba
  8. Asa (Culture): Ifira-Eni Sipo Omolakeji
  9. Lit (Literature): Awọn Ewi Kee-Kee-Kee
  10. Ede (Language): Aramupo: An, En, In, On, Un
  11. Asa (Culture): Ere Omode: Idaraya Akototita Ijakadi
See all 24 Basic 2 First Term Yoruba topics →
Downloads

Get Yoruba as PDF and Word

Every week of Basic 2 Yoruba, First Term, formatted and ready to print. Ad-free, and the copy lock comes off.

Get this term Card, bank transfer, USSD or OPay

Advertisement

Lesson Notes for Other Classes

Print it or edit it in Word

Every note is free to read online. A PDF or Word copy of one subject costs ₦1,000 for one term, or ₦2,000 for all three terms.

Continue with GoogleContinue with Facebook

Sign in first, then choose your class and subject at checkout.