Lesson note at a glance
- Class
- Basic 2
- Subject
- Yoruba
- Term
- Second Term
- Reading time
- 1 min
Take this term’s notes offline
Reading here is free. Download all 25 Basic 2 Yoruba Second term notes as PDF to print and Word to edit.
Download all three terms, ₦2,000Instant download. Secure payment by Paystack. Card, bank transfer, USSD or OPay. Payment stuck?
WhatsApp us.
AKOKO EKO: Iṣẹju 50
Apakan ede – aramupo faweli
AWON IFOJUSONA EKO: Akeko yoo le: i. So pàto àwon fawéli àramupo ti owà ii. Lo Okookan faweli na ninu oro iii. Dahun ibeere abe eko
KOKO EKO: AN – anan, iran, ikan, okan
- Gbolohun: “Anan dun lati je”
EN – eni, yen, ben, jen
- Gbolohun: “Eni wo ni o wa?”
IN – ina, rin, din, jin
- Gbolohun: “Ina n jo lori ebe”
ON – ona, pon, gon, son
- Gbolohun: “Ona yi gun ju”
UN – inu, gun, dun, kun
- Gbolohun: “Inu rẹ dun pupo”