Atunyewo Eko Lori Silebu Ede Yoruba, Elegbejegbe Tabi Irosiro SS3 Yoruba Lesson Note

Download Lesson Note
Lesson Notes

Topic: Atunyewo Eko Lori Silebu Ede Yoruba, Elegbejegbe Tabi Irosiro

EDE

AKOONU

Silebu ni ege oro ti o kere ju ti eemi le gbe jade leekan soso. Apeere:

Ajayi:          A-ja-yi  =    silebu meta

Olabisi        O-la-bi-si    silebu merin.

Adeleke      A-de-le-ke  silebu merin

Olopaa        O-lo-pa-a    silebu merin

Gbangbadekun  gba-n-gba-de-kun silebu marun-un.

 

Odo Silebu: ni apa ti o se pataki julo ninu ihun silebu kookan. Iro faweli ati iro konsonanti aranmupe asesilebu ni o maa n sise gege bi odo silebu. 

Odo silebu ni o maa n dun ju ninu silebu. 

Awon iro odo silebu ni a maa n gbo ju ninu oro.

Ori odo silebu ni a maa n fi ami ohun si

Kan-an-n-pa ni odo silebu je ninu ihun silebu.

Ap

wa                          

gba

sun

 

Apaala silebu -;je iro konsonanti yato si konsonanti aranmupe asesilebu [m,n] ni o maa n sise gege bi apaala silebu.

ap

gbo

dun

ko

we

 

IHUN SILEBU [F1,KF ATI N] NINU ORO OLOPO SILEBU.

Orisiirisii ona ni a le gba se ihunpo silebu ninu oro olopo silebu.

ORO                          IHUN                       IYE SILEBU

Aso                          A/ so                                   2

                                 f /kf        

Bata                         ba / ta                                  2     

                            Kf / kf

Igbale                      i/gba / le                              3

                           F/ kf /kf

Alupupu            A/lu/pu/pu                           4

                                 f/kf/kf/ kf

Konko                     ko/N/ko                               3

              Kf/N/kf      

 

IGBELEWON

  1. Kin ni silebu?
  2. Salaye ihun silebu pelu apeere.
  3. Pin awon oro yii si silebu

Agbalagbaakan

Olowolayemo

Gbangbalakoogbo

Oji ku tu ba-ra orunsaaro

Operekete

 

IGBELEWON

  1. Salaye ni ekunrere lori odo silebu ati apaala silebu pelu apeere.
  2. Eya ihun silebu meloo ni o wa? Fi apeere gbe idahun re lese.
  3. Ki ni pataki konsonanti aranmupe n ati m ninu ege silebu? 

IWE AKATILEWA

Aewoyin S.Y (2009) IMO, EDE, ASA ati LITIRESO YORUBA S.S.3 Copromutt Publishers.

 

ASA

ELEGBEJEGBE ORIKI ORISII IPA TI WON N KO NI AWUJO

AKOONU

  • Elegbejegbe ni egbe ti awon odo, agba ni okunrin tabi ni obinrin ti won je iro da sile ni agbegbe won fun igbega ilu ati ara won.

Ni aye atijo,iwonba ni ise ti ijoba maa n se fun awon ara ilu.igbega ati idagbasoke ilu tabi igberiko maa n waye pelu iranlowo awon elegbejegbe wonyi, apeere iru egbe bee ni aye atijo ni egbe ogboni.

Apapo awon agba ilu ti won to omo bii Aadota odun ni won maa n wo egbe ogboni. Ojuse egbe ogboni ni lati fun oba ni imoran.Won ni agbara lati da oba lekun tabi le oba kuro lori ite ti o ba si agbara lo.

         Ni ode-oni,awon elegbejegbe po jantirere. Apeere won ni :-

         Lion’s club

         Rotary club

         Majeeobaje

         Oredegbe ati bee bee lo.

Ni ilu tabi ileto ti awon egbe wonyii ba wa,orisiirisii ise idagbasoke ni won maa n se bii : – tite tabi titun afara se.

  • kiko ile ero kaakiri ibudoko.

 

IWULO ELEGBEJEGBE.

  1. Awon egbe ogboni maa n kopa ninu eto iselu awon baba-nla wa.
  2. Won maa n kopa ninu ise bii:- ona yiye,afara odo titun se,aafin oba kiko.
  3. Won maa n kopa ninu pipese owo ajemonu fun awon akekoo ile-iwe giga,pipese eko ofe fun awon akekoo ile-iwe girama,sisan owo idanwo iwe mewaa.
  4. Aaro kikojo,owe bibe,eesu kikojo fun  iranlowo egbe ati enikookan omo egbe.

 

IGBELEWON

  1. Nje egbejegbe ni anfaani Kankan ninu asa Yoruba bi? Se alaye kikun.
  2. Daruko egbejegbe ibile Yoruba marun-un ti o mo.

 

 

LITIRESO

OGBON ITOPINPIN LITIRESO

Akoonu:

Eyi ni awon koko to se pataki ti a gbodo mo nipa iwe litireso ti ijoba ya eyi ti a maa ka. Oun akoko ti a gbodo mo ni   oruko iwe, Oruko onkowe, ibudo itan, itan ni soki, awon eda itan, ona isowolo-ede, eko ti a ri ko, asa Yoruba ati beebee lo.

Iwe ti a maa gbe yewo ni  OMO TI A TI A FI ISE WO ati ORE MI.

Oruko Onkowe: oruko awon onkowe iwe naa ni: Ojukorola O. ati Aderibigbe M.

Ibudo Itan: n’ toka si ilu ti itan inu iwe yii ti waye, awon ilu ti itan naa ti waye ni:

Itan ni soki:

Awon Eda Itan:

Akanlo Ede Ayaworan: owe, akanlo ede, afiwe, awitunwi, asorege, ifohunpeniyan, iforodara abbl.

 

IWE AKATILEWA

Simplified Yoruba ati litireso

 

APAPO IGBELEWON

  1. a. Kin ni silebu?
  2. Salaye ihun silebu pelu apeere.
  3. Pin awon oro yii si silebu
  4. Nje egbejegbe ni anfaani Kankan ninu asa Yoruba bi? Se alaye kikun.
  5. Daruko egbejegbe ibile Yoruba marun-un ti o mo.

ATUNYEWO EKO

  1. Salaye iro konsonanti.
  2. Salaye iro faweli

 

ISE ASETILEWA

  1. ………ni ege oro ti eni lo gba jade leekansoso (a) oro (b) apola (d) silebu
  2.  ………..ni a n lo fun idagbasoke ilu. (a) iro (b) egbe (d) aaro.
  3. …………ni maa n gbo ju ninu silebu. (a) odo silebu (b) ihun silebu (d) apaala silebu.
  4. …… ki i se ara erongba elegbejegbe. (a) ona yiye (b) afara tite (d) aibowofagba.
  5. Apeere elegbejegbe laye atijo ni ………. (a) egbe onimototo (b) egbe ogboni (d) Rotary. 

THEORY

  1. a. ki ni silebu?
  1. salaye ihun silebu pelu apeere.
  1. a. kin ni odo ati apaala silebu? Fi idahun re han pelu apeere.
  1. kin ni elegbejegbe?
  2. salaye iwulo elegbejegbe merin ti o mo.

 

Lesson Notes for Other Classes